Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Pétérù 1:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pétérù, Àpósítélì Jésù Kírísítì,Sí àwọn àyànfẹ́ Ọlọ́run, ti wọ́n ń ṣe àtìpó ní àgbáyé, ti wọn tú káàkiri sí Pọ́ńtù, Gálátíà, Kápádókíà, Ésíà, àti Bítíníà,

Ka pipe ipin 1 Pétérù 1

Wo 1 Pétérù 1:1 ni o tọ