Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 9:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí mo ti jẹ́ òmìnira tí ń kò sì dara pọ̀ mọ́ ẹnikẹ́ni, mo sọ ara mi di ẹrú lọ́dọ̀ gbogbo ènìyàn, láti lè jèrè ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ sí i.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 9

Wo 1 Kọ́ríńtì 9:19 ni o tọ