Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 9:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní irú ipò báyìí, kí ni ẹ rò pé èrè mi ni láti jẹ́? Èrè mi ní àgbàyanu ayọ̀ tí mo ń rí gbà nípa ìwàásù ìyìn rere láèná ẹnikẹ́ni lówó, láìbéèrè ẹ̀tọ́ mi lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 9

Wo 1 Kọ́ríńtì 9:18 ni o tọ