Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 8:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n kì í ṣe gbogbo ènìyàn lo mọ èyí: Ṣùgbọ́n àwọn ẹlòmíràn tí ó ti ń bọ̀rìṣà lọ́jọ́ tó ti pẹ́ títí di ìsinsinyìí jẹ ẹ́ bí ohun tí a fi rúbọ sí òrìṣà; àti ẹ̀rì-ọkàn wọn tí ó ṣe àìlera sì di aláìmọ́.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 8

Wo 1 Kọ́ríńtì 8:7 ni o tọ