Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 8:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ kíyèsára, nítorí bi ẹnìkan ba rí i ti iwọ ti o ni ìmọ̀ bá jókòó ti oúnjẹ ní ilé òrìṣà, ǹjẹ́ òun kò ha ni mú ọkàn le, bi ẹ̀rí-ọkàn rẹ̀ bá ṣe aláìlera, lati jẹ oúnjẹ tí a fi rúbọ sí òrìsà?

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 8

Wo 1 Kọ́ríńtì 8:10 ni o tọ