Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 8:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìsinsinyìí, nípa tí oúnjẹ ti a fi rúbọ sí òrìṣà, a mọ̀ pé gbogbo wa ni a ní ìmọ̀, ìmọ̀ a máa fẹ́ mu ní gbéraga, ṣùgbọ́n ìfẹ́ ní i gbéni ró.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 8

Wo 1 Kọ́ríńtì 8:1 ni o tọ