Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 6:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣé ẹ̀yin kò mọ̀ pé àwọn ẹni mímọ́ ni yóò ṣe ìdájọ́ ayé? Ǹjẹ́ bí ó ba ṣe ìpaṣẹ̀ yín ni a ti ṣe ìdájọ́ ayé, kí ni ìdí tí ẹ kò fi yanjú àwọn ọ̀rọ̀ kéékèèkéé wọ̀nyí láàrin ara yín.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 6

Wo 1 Kọ́ríńtì 6:2 ni o tọ