Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 4:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ta ni ó mú ọ yàtọ̀ sí àwọn ẹlòmíràn? Kí ni ìwọ ni tí ìwọ kò rí gbà? Tí ìwọ ba sì gbà á, è é ti ṣe tí ìwọ fi ń halẹ̀ bí ẹni pé ìwọ kò gba á?

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 4

Wo 1 Kọ́ríńtì 4:7 ni o tọ