Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 4:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ kíyèsí i pé, mo ti fi ara mi àti Àpólò ṣe àpẹrẹ nǹkan tí mo wí, pé kí ẹ̀yin lè ti ipa wa kọ́ láti máa ṣe ohun tí a ti kọ̀wé kọjá. “Kí ẹnikẹ́ni nínú yín má ṣe titorí ẹnìkan gbéraga sí ẹnìkejì.”

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 4

Wo 1 Kọ́ríńtì 4:6 ni o tọ