Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 4:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn ń kẹ́gàn wa, àwa ń bẹ̀bẹ̀. Títí di ìsinsinyìí ni a ti wà bí ohun ẹ̀gbin ayé, bí orí àkìtàn gbogbo ayé.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 4

Wo 1 Kọ́ríńtì 4:13 ni o tọ