Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 3:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tí ó ń gbìn àti ẹni tí ó ń bomi rín ní ìrònú kan àti èrèdí kan, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹnìkọ̀ọ̀kan wa yóò gba èrè tirẹ̀, gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe é kárakára tó.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 3

Wo 1 Kọ́ríńtì 3:8 ni o tọ