Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 2:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnikẹ́ni tí kò bá jẹ́ ti Ẹ̀mí kò lè gba àwọn ohun tí ó wá láti ọ̀dọ̀ Ẹ̀mi Mímọ́, nítorí wọ́n jẹ́ ohun wèrè sí, kò sì le ye e, nítorí nípa tí Ẹ̀mí ní a fi ń wádìí wọn.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 2

Wo 1 Kọ́ríńtì 2:14 ni o tọ