Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 11:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣé ẹ̀yin kò ní ilé tí ẹ ti lè jẹ, tí ẹ sì ti lè mu ni? Tàbí ẹ̀yin ń gan ìjọ Ọlọ́run ni? Ẹ̀yin sì ń dójútì àwọn aláìní? Kí ni kí èmi ó wí fún un yín? Èmi yóò ha yìn yín nítorí èyí? A! Rárá o. Èmi kọ́, n kò ní yìn yín.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 11

Wo 1 Kọ́ríńtì 11:22 ni o tọ