Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 11:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lọ́nà kínní, mo gbọ́ pe ìyapa máa ń wà láàrin yín ní ìgbà tí ẹ bá pé jọ pọ̀ gẹ́gẹ́ bí Ìjọ, mo sì gba èyí gbọ́ dé ààyè ibìkan.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 11

Wo 1 Kọ́ríńtì 11:18 ni o tọ