Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 11:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹ máa tẹ̀lé àpẹẹrẹ mi, gẹ́gẹ́ bí èmi náà ti ń tẹ̀lé àpẹẹrẹ Kírísítì.

2. Èmí yìn yín fún rírántí mi nínú ohun gbogbo àti fún didi gbogbo ẹ̀kọ́ tí mo kọ́ ọ yín mú sinsin gẹ́gẹ́ bí mo ṣe fi lélẹ̀ fún un yín.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 11