Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 10:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Rárá, ṣùgbọ́n ohun tí mo ń wí ni pé, ohun tí àwọn aláìkọlà fi ń rúbọ wọn sí àwọn ẹ̀mí èsù. Dájúdájú kì í ṣe ìrúbọ sí Ọlọ́run. Èmi kò sì fẹ́ kí ẹnikẹ́ni nínú yín so ara rẹ̀ pọ̀ mọ́ ẹ̀mí èṣù.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 10

Wo 1 Kọ́ríńtì 10:20 ni o tọ