Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 10:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò sí ìdànwò kan tí ó ti bá yín, bí kò ṣe irú èyí tí ó ti bá ènìyàn rí, ṣùgbọ́n olódodo ni Ọlórun, ẹni ti kì yóò jẹ́ kí á dán an yín wò ju bí ẹ̀yin ti le gbà, ṣùgbọ̀n tí yóò sì ṣe ọ̀nà àbáyọ pẹ̀lú nínú ìdánwò náà, kí ẹ́yin baà lè faradà á.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 10

Wo 1 Kọ́ríńtì 10:13 ni o tọ