Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 1:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohun tí mo ń sọ ni pé: Olúkúlùku yín ń wí pé, “Èmí tẹ̀lé Pọ́ọ̀lù”; “Èmi tẹ̀lé Àpólò”; òm̀íràn, “Èmi tẹ̀lé Kéfà, ìtúmọ̀, Pétérù”; àti ẹlòmìíràn, “Èmi tẹ̀lé Kírísítì.”

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 1

Wo 1 Kọ́ríńtì 1:12 ni o tọ