Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 1:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pọ́ọ̀lù, ẹni ti a pé láti jẹ́ àpósítélì Kírísítì Jésù nípa ìfẹ́ Ọlọ́run àti Sósíténì arákùnrin wa.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 1

Wo 1 Kọ́ríńtì 1:1 ni o tọ