Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Jòhánù 5:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa èyí ni àwa mọ̀ pé àwa fẹ́ràn àwọn ọmọ Ọlọ́run, nígbà tí a bá fẹ́ràn Ọlọ́run, tí a sì ń pa òfin rẹ̀ mọ́.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 5

Wo 1 Jòhánù 5:2 ni o tọ