Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Jòhánù 5:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúkúlùkù ẹni tí ó bá gbàgbọ́ pé Jésù ni Kírísítì, a bí i nípa ti Ọlọ́run: àti olúkúlùkù ẹni tí ó fẹ́ràn. Ẹni tí ó bi nì, ó fẹ́ràn ẹni tí a bí nípaṣẹ̀ rẹ̀ pẹ̀lú.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 5

Wo 1 Jòhánù 5:1 ni o tọ