Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Jòhánù 4:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olùfẹ́, ẹ jẹ́ kí a fẹ́ràn ara wa: nítorí ìfẹ́ ti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wá; àti gbogbo ẹni tí ó bá ní ìfẹ́, a bí i nípa ti Ọlọ́run, ó sì mọ Ọlọ́run.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 4

Wo 1 Jòhánù 4:7 ni o tọ