Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Jòhánù 4:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ti Ọlọ́run ni àwa: ẹni tí ó bá mọ Ọlọ́run, ó ń gbọ́ tiwa; ẹni tí kì í ṣe ti Ọlọ́run kò ni gbọ́ ti wa. Nípa èyí ni àwa mọ ẹ̀mí òtítọ́, àti ẹ̀mí èké.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 4

Wo 1 Jòhánù 4:6 ni o tọ