Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Jòhánù 2:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti nísinsin yìí, ẹ̀yin ọmọ mi ọ̀wọ́n, ẹ máa gbé inú rẹ̀, pé nígbà tí òun ó bá farahàn, kí a lè ni ìgboyà níwájú rẹ̀, kí ojú má sì tì wá níwájú rẹ̀ ni ìgbà wíwá rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 2

Wo 1 Jòhánù 2:28 ni o tọ