Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Jòhánù 2:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ń kọ̀wé sí yín, ẹ̀yin baba,nítorí ti ẹ̀yin tí mọ ẹni tí o wà ni àtètékọṣe.Èmi ń kọ̀wé sí yín, ẹ̀yin ọ̀dọ́mọkùnrin,nítorí tí ẹ̀yin ni agbára,tí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run sì ń gbé nínú yín,tí ẹ sì ṣẹ́gun ẹni ibi náà.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 2

Wo 1 Jòhánù 2:14 ni o tọ