Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 9:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ kún fún ayọ̀, ẹ̀yin ọmọbìnrin ṢíónìẸ hó ìhó ayọ̀, ẹ̀yin ọmọbìnrin Jérúsálẹ́mù:Ẹ wo ọba yín ń bọ̀ wá ṣọ́dọ̀ yín:òdodo ni òun, ó sì ní ìgbàlà;ó ní ìrẹ̀lẹ̀, ó sì ń gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́,àní ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́.

Ka pipe ipin Sekaráyà 9

Wo Sekaráyà 9:9 ni o tọ