Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 9:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ó sì gbé kẹ̀kẹ́ kúrò ni Éfúráímù,àti ẹṣin ogun kúrò ni Jérúsálẹ́mù,a ó sì ṣẹ́ ọrun ogun.Òun yóò sì kéde àlàáfíà sí àwọn aláìkọlà.Ìjọba rẹ̀ yóò sì gbilẹ̀ láti òkun dé òkun,àti láti odò títí de òpin ayé.

Ka pipe ipin Sekaráyà 9

Wo Sekaráyà 9:10 ni o tọ