Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 9:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ásíkélónì yóò rí í, yóò sì bẹ̀rù;Gásà pẹ̀lú yóò rí í, yóò sì káànú gidigidi,àti Ékírónì: nítorí tí ìrètí rẹ̀ yóò sákì í.Gásà yóò pàdánu ọba rẹ̀,Ásíkélónì yóò sì di ahoro.

Ka pipe ipin Sekaráyà 9

Wo Sekaráyà 9:5 ni o tọ