Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 8:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò ṣi ṣe, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yin tí jẹ́ ègún láàrin àwọn aláìkọlà, ẹ̀yin ilé Júdà, àti ilé Íṣrẹ́lì, bẹ́ẹ̀ ni èmi ó gbà yín sílẹ̀; ẹ̀yin o sì jẹ́ ìbùkún: ẹ má bẹ̀rù, ṣùgbọ́n jẹ́ ki ọwọ́ yín le.”

Ka pipe ipin Sekaráyà 8

Wo Sekaráyà 8:13 ni o tọ