Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 8:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí irúgbìn yóò gbilẹ̀: àjàrà yóò ṣo èṣo rẹ̀, ilẹ̀ yóò sì hu ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ nǹkan rẹ̀ jáde, àwọn ọ̀run yóò sì mu ìrì wọn wá; èmi ó sì mu kí èyí jẹ ogún ìní àwọn ìyókù ènìyàn yìí ni gbogbo nǹkan wọ̀nyí.

Ka pipe ipin Sekaráyà 8

Wo Sekaráyà 8:12 ni o tọ