Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 7:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti láti bá àwọn àlùfáà tí ó wà ní ilé Olúwa àwọn ọmọ-ogun, àti àwọn wòlíì sọ̀rọ̀ wí pé, “Ṣé kí èmi ó sọkún ní oṣù kárùnún kí èmi ya ara mi sọ́tọ̀, bí mo ti ń ṣe láti ọdún mélòó wọ̀nyí wá bí?”

Ka pipe ipin Sekaráyà 7

Wo Sekaráyà 7:3 ni o tọ