Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 7:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ṣe ní ọdún kẹrin Dáríúsì ọba, ọ̀rọ̀ Olúwa tọ́ Sekaráyà wá ni ọjọ́ kẹrin oṣù Kísíléfì tí ń se oṣù kẹsàn-án.

Ka pipe ipin Sekaráyà 7

Wo Sekaráyà 7:1 ni o tọ