Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 5:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì wí pé, “Kí ni nǹkan náà?”Ó sì wí pé, “Èyí ni òṣùwọ̀n éfà tí ó jáde lọ.” Ó sì wí pé, “Èyí ni àwòrán ní gbogbo ilẹ̀ ayé.”

Ka pipe ipin Sekaráyà 5

Wo Sekaráyà 5:6 ni o tọ