Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 5:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

‘Èmi o mú un jáde,’ ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí, ‘yóò si wọ inú ilé olè lọ, àti inú ilé ẹni ti o bá fi ọrúkọ mi búra èké: yóò si wà ni àárin ilé rẹ̀, yóò si rún un pẹ̀lú igi àti òkúta inú rẹ̀.’ ”

Ka pipe ipin Sekaráyà 5

Wo Sekaráyà 5:4 ni o tọ