Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 3:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mó sì wí pé, “Jẹ kí wọn fi gèlè mímọ́ wé e lórí.” Wọn si fi gèlè mímọ́ wé e lorí, wọn si fi aṣọ wọ̀ ọ́. Ańgẹ́lì Olúwa sì dúró tì í.

Ka pipe ipin Sekaráyà 3

Wo Sekaráyà 3:5 ni o tọ