Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 3:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì dáhùn ó wí fún àwọn tí ó dúró níwájú rẹ̀ pé, “Bọ́ aṣọ èérí nì kúrò ní ara rẹ̀.”Ó sì wí fún Jóṣúà pé, “Wòó, mo mú kí àìṣedéédé rẹ̀ kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀, èmi yóò sì wọ̀ ọ́ ní aṣọ ẹ̀yẹ.”

Ka pipe ipin Sekaráyà 3

Wo Sekaráyà 3:4 ni o tọ