Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 2:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Áà! Áà! Sá kúrò ni ilẹ̀ àriwá, ni Olúwa wí; nítorí pé bí afẹ́fẹ́ mẹ́rin ọ̀run ni mo tú yín kákiri,” ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Sekaráyà 2

Wo Sekaráyà 2:6 ni o tọ