Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 2:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀-èdè ni yóò dàpọ̀ mọ́ Olúwa ní ọjọ́ náà, wọn yóò sì di ènìyàn mi: èmi yóò sì gbé àárin rẹ, ìwọ yóò sì mọ̀ pé, Olúwa àwọn ọmọ-ogun ni ó rán mi sí ọ.

Ka pipe ipin Sekaráyà 2

Wo Sekaráyà 2:11 ni o tọ