Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 14:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹṣẹ̀ rẹ̀ yóò sì dúró ni ọjọ́ náà lórí òkè Ólífì, tí ó wà níwájú Jérúsálẹ́mù ni ila-oòrùn, òkè Ólífì yóò sì làá sí méjì, sí ìhà ilà-oòrùn àti ìhà ìwọ̀-oòrun, àfonífojì ńláńlá yóò wà: ìdajì òké náà yóò sì sí síhà àríwá, àti ìdajì rẹ̀ síhà gúṣù.

Ka pipe ipin Sekaráyà 14

Wo Sekaráyà 14:4 ni o tọ