Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 14:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ náà ni “MÍMỌ́ SÍ Olúwa” yóò wà lára ṣaworo ẹṣin: àti àwọn ìkòkò ni ilé Olúwa yóò sì dàbí àwọn ọpọ́n tí ń bẹ níwájú pẹpẹ.

Ka pipe ipin Sekaráyà 14

Wo Sekaráyà 14:20 ni o tọ