Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 13:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ó sì mú apá kẹ́ta náà la àárin iná,èmi yóò sì yọ́ wọn bí a ti yọ́ fàdákà,èmi yóò sì dán wọn wò, bi a tí ń dán góòlu wò:wọn yóò sì pé orúkọ mi,èmi yóò sì dá wọn lóhùn:èmi yóò wí pé, ‘Àwọn ènìyàn mi ni,’àwọn yóò sì wí pé, ‘Olúwa ni Ọlọ́run wa.’ ”

Ka pipe ipin Sekaráyà 13

Wo Sekaráyà 13:9 ni o tọ