Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 13:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Yóò sì ṣe ní ọjọ́ náà ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí, ni èmi ó gé orúkọ àwọn òrìṣà kúrò ni ilẹ̀ náà, a kì yóò sì rántí wọn mọ́: àti pẹ̀lú èmi ó mú àwọn wòlíì èké àti àwọn ẹ̀mí àìmọ́ kọjá kúrò ni ilẹ̀ náà.

Ka pipe ipin Sekaráyà 13

Wo Sekaráyà 13:2 ni o tọ