Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 1:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo rí ìran kan ni òru, si wò ó, ọkùnrin kan ń gun ẹṣin púpa kan, òun sì dúró láàrin àwọn igi míritílì tí ó wà ní ibi òòji; lẹ́yìn rẹ̀ si ni ẹ̀ṣin púpa, adíkálà, àti funfun gbé wà.

Ka pipe ipin Sekaráyà 1

Wo Sekaráyà 1:8 ni o tọ