Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 1:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kọkànlá, tí ó jẹ́, oṣù Sébátì, ní ọdún kejì Dáríúsì, ni ọ̀rọ̀ Olúwa tọ Sekaráyà, ọmọ Berekáyà ọmọ Idò wòlíì wá, pé,

Ka pipe ipin Sekaráyà 1

Wo Sekaráyà 1:7 ni o tọ