Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sefanáyà 2:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ wá Olúwa, gbogbo ẹ̀yin onírẹ̀lẹ̀ ilẹ̀ náà,ẹ̀yin tí ń ṣe ohun tí ó bá pa láṣẹ.Ẹ wá òdodo, ẹ wá ìrẹ̀lẹ̀ pẹ̀lú,bóyá á ó pa yín mọ́ ní ọjọ́ ìbínú Olúwa.

Ka pipe ipin Sefanáyà 2

Wo Sefanáyà 2:3 ni o tọ