Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sefanáyà 2:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni ìlú aláyọ̀ tí ó ń gbé láìléwu.Ó sì sọ sí ara rẹ̀ pé,“Èmi ni, kò sì sí ẹnìkan tí ó ń bẹ lẹ́yìn mi.”Irú ahoro wo ni òun ha ti jẹ́,ibùgbé fún àwọn ẹranko igbó!Gbogbo ẹni tí ó bá kọjá ọ̀dọ̀ rẹ̀yóò fi rẹ́rìnín ẹlẹ́yà,wọ́n yóò sì gbọn ẹsẹ̀ wọn.

Ka pipe ipin Sefanáyà 2

Wo Sefanáyà 2:15 ni o tọ