Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sefanáyà 2:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Agbo ẹran yóò sì dùbúlẹ̀ ṣíbẹ̀àti gbogbo ẹ̀dá ní orísìírísìí.Òwìwí ihà àti dídún bí ẹyẹ òwìwíyóò wọ bí ẹyẹ ni ọwọ́n rẹ̀.Ohùn wọn yóò kọrin ni ojú fèrèsé,ìdahoro yóò wà nínú ìloro ẹnu ọ̀nà,òun yóò sì ṣẹ́ kédárì sílẹ̀.

Ka pipe ipin Sefanáyà 2

Wo Sefanáyà 2:14 ni o tọ