Èmi yóò sì mú ìpọ́njú wá sóríènìyàn, wọn yóò sì máa rìn gẹ́gẹ́ bí afọ́jú,nítorí àwọn ti dẹ́ṣẹ̀ sí Olúwa.Ẹ̀jẹ̀ wọn ni a ó sì tú jáde bí erukuàti ẹran-ara wọn bí ìgbẹ́.