Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 94:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Olúwa Ọlọ́run ẹni tí ń gbẹ̀san,Ọlọ́run ẹni tí ń gbẹ̀san.

2. Gbé ara Rẹ sókè, ìwọ onídàájọ́ ayé;san ẹ̀san fún agbéragaohun tí ó yẹ wọ́n.

Ka pipe ipin Sáàmù 94