Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 91:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹni tí ó gbé ibi ìkọ̀kọ̀ ọ̀gá ògoni yóò sinmi ní ibi òjìji Olódùmarè.

2. Èmi yóò sọ nípa ti Olúwa pé,“Òun ní ààbò àti odi mi,Ọlọ́run mi, ẹni tí èmi gbẹ́kẹ̀lé”.

3. Ní tòótọ́ òun yóò gbà mí nínúìdẹkùn àwọn pẹyẹ pẹyẹàti nínú àjàkálẹ̀-àrùn búburú.

Ka pipe ipin Sáàmù 91